Ní ọ̀sẹ̀ yìí lórí ètò Ìwòyé: Olùkọ́ Maryam Usman sòfò ẹ̀mí lẹ́yìn tí bàbá akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ lù ú ní àlùbami; àwọn ẹ̀ṣọ́ ààbò gba àwọn ọmọ méjì là lọ́wọ́ àwọn ajínigbé ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́; ìkún omi ojijì dá omiyálẹ̀ sí ilé ní Ìlú Èkó…
Continue reading the complete report from the original publisher.
Read Full Story